FANDOM


Herb Kurowa

Abule kan ni ila-oorun gusu ile Polandi ni o n je Kuro. O wa laarin Pulawi ati Lubiliini. Ilu ti awon kan jumo da sile ni. Ibe ni won ti n ta awon ounje ti won n pese ni agbegbe re. Awon ile-ise ti won ti n fi awo eran se nnkan wa ni ibe pelu. Ni senturi kerindinlogun, ibe ni awon ti o n se Kafinisiimu (Calvinism) ti maa n pe jo nitori pe ibe ni awon kan ti won n pe 'polish brethren' maa n gbe. nigba ti yoo fi di odun 1660, opolopo ninu awon eniyan ibe ti yi pada si esin arianisiimu (Arianism).

Ad blocker interference detected!


Wikia is a free-to-use site that makes money from advertising. We have a modified experience for viewers using ad blockers

Wikia is not accessible if you’ve made further modifications. Remove the custom ad blocker rule(s) and the page will load as expected.

Więcej z Fandomu

Losowa wiki